Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó da òrùka mẹrin, ó jó ọ̀kọ̀ọ̀kan mọ́ igun kọ̀ọ̀kan ayanran idẹ náà, àwọn òrùka wọnyi ni wọ́n máa ń ti ọ̀pá bọ̀ láti fi gbé pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:5 ni o tọ