Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Lára rẹ̀ ni wọ́n ti ṣe ìtẹ́lẹ̀ àwọn òpó àgọ́ náà yípo ati àwọn èèkàn àgọ́ ati àwọn èèkàn àgbàlá inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:31 ni o tọ