Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Òpó mẹrin ni aṣọ títa tí ẹnu ọ̀nà yìí ní, pẹlu ìtẹ́lẹ̀ idẹ mẹrin. Fadaka ni wọ́n fi ṣe àwọn ìkọ́ ati àwọn ọ̀pá tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́, fadaka ni wọ́n sì fi bo àwọn ìbòrí òpó náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:19 ni o tọ