Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gígùn aṣọ títa fún apá ìwọ̀ oòrùn jẹ́ aadọta igbọnwọ, òpó rẹ̀ jẹ́ mẹ́wàá, àwọn àtẹ̀bọ̀ rẹ̀ náà jẹ́ mẹ́wàá; fadaka ni wọ́n fi ṣe àwọn ìkọ́ ati àwọn ọ̀pá tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:12 ni o tọ