Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogún ni àwọn òpó aṣọ títa, àwọn ìtẹ́lẹ̀ wọn náà sì jẹ́ ogún. Idẹ ni ó fi ṣe ìtẹ́lẹ̀ wọn, ṣugbọn fadaka ni ó fi ṣe ìkọ́ ati àwọn ọ̀pá tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:10 ni o tọ