Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 36:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi aṣọ aláwọ̀ aró, ati ti elése àlùkò, ati aṣọ pupa, ati aṣọ funfun onílà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ ṣe aṣọ títa fún ẹnu ọ̀nà, wọ́n sì ṣe iṣẹ́ ọnà aláràbarà sí i lára.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:37 ni o tọ