Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 36:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Aṣọ aláwọ̀ aró, ati ti elése àlùkò, ati aṣọ pupa ati aṣọ funfun onílà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ ni wọ́n fi ṣe aṣọ àgọ́ náà, wọ́n sì ya àwòrán Kerubu sí i lára.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:35 ni o tọ