Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 36:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àkànpọ̀ igi náà wà lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ ní ìsàlẹ̀, ṣugbọn wọ́n so wọ́n pọ̀ ní òkè ní ibi òrùka kinni, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe àwọn àkànpọ̀ igi kinni ati ekeji fún igun mejeeji àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:29 ni o tọ