Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 36:24 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n sì ṣe ogoji ìtẹ́lẹ̀ fadaka tí wọ́n fi sí abẹ́ ogún àkànpọ̀ igi náà, ìtẹ́lẹ̀ meji meji lábẹ́ àkànpọ̀ igi kọ̀ọ̀kan fún àwọn ìkọ́ rẹ̀ mejeeji.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:24 ni o tọ