Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 35:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n lè fi fadaka ati idẹ tọrẹ fún OLUWA ni wọ́n mú wọn wá, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn tí wọ́n ní igi akasia, tí ó wúlò náà mú wọn wá pẹlu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 35

Wo Ẹkisodu 35:24 ni o tọ