Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 35:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí wá, atọkunrin atobinrin, gbogbo àwọn tí ó tinú ọkàn wọn wá, wọ́n mú yẹtí wúrà wá, ati òrùka wúrà, ati ẹ̀gbà wúrà, ati oríṣìíríṣìí ohun èlò mìíràn tí wọ́n fi wúrà ṣe; olukuluku wọn mú ẹ̀bùn wúrà wá fún OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 35

Wo Ẹkisodu 35:22 ni o tọ