Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 35:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹpẹ ẹbọ sísun tòun ti ojú ààrò onídẹ rẹ̀, pẹlu àwọn ọ̀pá rẹ̀ ati àwọn ohun èlò tí ó jẹ mọ́ ti pẹpẹ ẹbọ, agbada omi ati ìtẹ́lẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 35

Wo Ẹkisodu 35:16 ni o tọ