Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 34:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli ṣe akiyesi ojú Mose, pé ó ń kọ mànàmànà; Mose a sì máa fi aṣọ ìbòjú bo ojú rẹ̀ títí yóo fi di ìgbà tí yóo tún wọ ilé lọ láti bá OLUWA sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:35 ni o tọ