Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 34:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọjọ́ mẹfa ni kí ẹ fi ṣe iṣẹ́ yín, ní ọjọ́ keje ẹ gbọdọ̀ sinmi; kì báà ṣe àkókò oko ríro, tabi àkókò ìkórè, dandan ni kí ẹ sinmi.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:21 ni o tọ