Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 33:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan gbọ́ ìròyìn burúkú náà, ọkàn wọn bàjẹ́, kò sì sí ẹni tí ó fi ohun ọ̀ṣọ́ sí ara rárá.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:4 ni o tọ