Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 33:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tún pe Mose, ó ní, “Dìde kúrò níhìn-ín, ìwọ ati àwọn eniyan tí o kó wá láti ilẹ̀ Ijipti, ẹ lọ sí ilẹ̀ tí mo ti búra fún Abrahamu, ati fún Isaaki, ati fún Jakọbu pé n óo fún arọmọdọmọ wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:1 ni o tọ