Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 32:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni gba wúrà náà lọ́wọ́ wọn, ó lo irinṣẹ́ àwọn alágbẹ̀dẹ, ó fi wúrà náà da ère ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù kan. Àwọn eniyan náà bá dáhùn pé, “Ẹ̀yin eniyan Israẹli, ọlọrun yín tí ó mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti nìyí.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:4 ni o tọ