Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 32:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Pada lọ nisinsinyii, kí o sì kó àwọn eniyan náà lọ sí ibi tí mo sọ fún ọ. Ranti pé angẹli mi yóo máa ṣáájú yín lọ, ṣugbọn ọjọ́ ń bọ̀, tí n óo jẹ àwọn eniyan náà níyà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:34 ni o tọ