Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 32:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, Mose wí fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ ti dẹ́ṣẹ̀ ńlá, n óo tún gòkè tọ OLUWA lọ, bóyá n óo lè ṣe ètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ yín.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:30 ni o tọ