Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 32:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni bá sọ fún wọn pé, “Ẹ gba gbogbo yẹtí wúrà etí àwọn aya yín jọ, ati ti àwọn ọmọkunrin yín, ati ti àwọn ọmọbinrin yín, kí ẹ sì kó wọn wá.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:2 ni o tọ