Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 32:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá yipada, ó sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè, tòun ti wàláà òkúta ẹ̀rí mejeeji lọ́wọ́ rẹ̀, àwọn wàláà òkúta tí Ọlọrun ti kọ nǹkan sí lójú mejeeji.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:15 ni o tọ