Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 31:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ náà jẹ́ àmì ayérayé tí ó wà láàrin èmi ati àwọn eniyan Israẹli, pé ọjọ́ mẹfa ni èmi Ọlọrun fi dá ọ̀run ati ayé, ati pé ní ọjọ́ keje, mo dáwọ́ iṣẹ́ ṣíṣe dúró, mo sì sinmi.’ ”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 31

Wo Ẹkisodu 31:17 ni o tọ