Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 31:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, ‘Ẹ pa ọjọ́ ìsinmi mi mọ́, nítorí pé òun ni àmì tí ó wà láàrin èmi pẹlu yín ní ìrandíran yín; kí ẹ lè mọ̀ pé, èmi OLUWA yà yín sọ́tọ̀ fún ara mi.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 31

Wo Ẹkisodu 31:13 ni o tọ