Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 30:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Bù ninu rẹ̀, kí o gún un lúbúlúbú. Lẹ́yìn náà, bù díẹ̀ ninu lúbúlúbú yìí, kí o fi siwaju àpótí ẹ̀rí ninu àgọ́ àjọ, níbi tí n óo ti bá ọ pàdé, yóo jẹ́ mímọ́ fún yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:36 ni o tọ