Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wọn yóo gbọ́rọ̀ sí ọ lẹ́nu, ìwọ ati àwọn àgbààgbà Israẹli yóo tọ ọba Ijipti lọ, ẹ óo sì wí fún un pé, ‘OLUWA Ọlọrun àwọn Heberu ti wá bá wa, jọ̀wọ́, jẹ́ kí á lọ sinu aṣálẹ̀, ní ìwọ̀n ìrìn ọjọ́ mẹta, kí á lè rúbọ sí OLUWA, Ọlọrun wa.’

Ka pipe ipin Ẹkisodu 3

Wo Ẹkisodu 3:18 ni o tọ