Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 27:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Aṣọ títa kan yóo wà ní ẹ̀gbẹ́ keji ẹnu ọ̀nà náà, òun náà yóo gùn ní igbọnwọ mẹẹdogun, yóo sì ní òpó mẹta ati ìtẹ́lẹ̀ mẹta bákan náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 27

Wo Ẹkisodu 27:15 ni o tọ