Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 26:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí o gbé tabili kalẹ̀ ní ọwọ́ òde aṣọ títa náà, kí ọ̀pá fìtílà wà ní apá ìhà gúsù àgọ́ náà, ní òdìkejì tabili náà, kí o sì gbé tabili náà kalẹ̀ ní apá àríwá.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:35 ni o tọ