Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 26:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Lára àwọn àtẹ̀bọ̀ ni kí o fi àwọn aṣọ títa náà kọ́, kí o sì gbé àpótí ẹ̀rí náà wọ inú ibi tí aṣọ títa náà wà, aṣọ títa yìí ni yóo ya ibi mímọ́ sọ́tọ̀ kúrò lára ibi mímọ́ jùlọ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:33 ni o tọ