Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 26:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí àwọn àkànpọ̀ igi mejeeji tí wọ́n wà ní igun àgọ́ wà ní ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ìsàlẹ̀, ṣugbọn kí o so wọ́n pọ̀ ní òkè ní ibi ìtẹ̀bọ̀ àkọ́kọ́. Bẹ́ẹ̀ ni kí o ṣe àwọn àkànpọ̀ igi mejeeji tí wọ́n wà ní igun mejeeji.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:24 ni o tọ