Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 25:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbé tabili náà kalẹ̀ níwájú àpótí ẹ̀rí, kí burẹdi ìfihàn sì máa wà ní orí rẹ̀ nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 25

Wo Ẹkisodu 25:30 ni o tọ