Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 25:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kí wọ́n fi igi akasia kan àpótí kan, kí ó gùn ní ìwọ̀n igbọnwọ meji ààbọ̀, kí ó fẹ̀ ní igbọnwọ kan ààbọ̀, kí ó sì ga ní igbọnwọ kan ààbọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 25

Wo Ẹkisodu 25:10 ni o tọ