Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni Mose bá gba ẹ̀jẹ̀ ẹran yòókù tí ó wà ninu àwo, ó wọ́n ọn sí àwọn eniyan náà lára, ó ní, “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ majẹmu tí OLUWA bá yín dá, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí mo sọ.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 24

Wo Ẹkisodu 24:8 ni o tọ