Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá tọ àwọn eniyan náà lọ, ó sọ gbogbo ohun tí OLUWA sọ fún un fún wọn, ati gbogbo ìlànà tí ó là sílẹ̀, gbogbo àwọn eniyan náà sì fi ẹnu kò, wọ́n dáhùn pé, “Gbogbo ohun tí OLUWA wí ni a óo ṣe.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 24

Wo Ẹkisodu 24:3 ni o tọ