Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún Mose pé, “Ẹ gòkè tọ èmi OLUWA wá, ìwọ ati Aaroni, ati Nadabu, ati Abihu, ati aadọrin ninu àwọn àgbààgbà Israẹli, kí ẹ sì sin èmi OLUWA ní òkèèrè.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 24

Wo Ẹkisodu 24:1 ni o tọ