Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 23:7 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ fi ẹ̀sùn èké kan ẹnikẹ́ni, o kò sì gbọdọ̀ pa aláìṣẹ̀ tabi olódodo nítorí pé, èmi, OLUWA kò ní dá eniyan burúkú láre.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:7 ni o tọ