Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ẹni tí ó kórìíra rẹ, tí ẹrù wó kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà mọ́lẹ̀, tí kò lè lọ mọ́, o kò gbọdọ̀ gbójú kúrò kí o fi sílẹ̀ níbẹ̀, o níláti bá a sọ ẹrù náà kalẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:5 ni o tọ