Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 23:32-33 BIBELI MIMỌ (BM)

32. Ẹ kò gbọdọ̀ bá àwọn tabi àwọn oriṣa wọn dá majẹmu.

33. Wọn kò gbọdọ̀ gbé orí ilẹ̀ yín, kí wọ́n má baà mú yín ṣẹ èmi OLUWA; nítorí pé bí ẹ bá bọ oriṣa wọn, ọrùn ara yín ni ẹ tì bọ tàkúté.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23