Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 23:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi OLUWA Ọlọrun yín ni kí ẹ máa sìn. N óo pèsè ọpọlọpọ nǹkan jíjẹ ati nǹkan mímu fún yín, n óo sì mú àìsàn kúrò láàrin yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:25 ni o tọ