Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnìkan bá fi owó tabi ìṣúra kan pamọ́ sí ọwọ́ aládùúgbò rẹ̀, tí olè bá gbé e lọ mọ́ aládùúgbò rẹ̀ yìí lọ́wọ́, bí ọwọ́ bá tẹ olè yìí, ìlọ́po meji ohun tí ó gbé ni yóo fi san.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 22

Wo Ẹkisodu 22:7 ni o tọ