“O kò gbọdọ̀ jáfara láti mú ninu ọpọlọpọ ọkà rẹ ati ọpọlọpọ ọtí waini rẹ láti fi rúbọ sí mi.“O níláti fún mi ní àkọ́bí rẹ ọkunrin pẹlu.