Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnìkan bá fún aládùúgbò rẹ̀ ní ẹran sìn, kì báà ṣe kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tabi mààlúù, tabi aguntan, bí ẹran náà bá kú tabi kí ó farapa, tabi tí ó bá rìn lọ tí kò sì sí ẹni tí ó rí i,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 22

Wo Ẹkisodu 22:10 ni o tọ