Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnìkan bá jí akọ mààlúù kan tabi aguntan kan gbé, tí ó bá pa á, tabi tí ó tà á, yóo san akọ mààlúù marun-un dípò ẹyọ kan ati aguntan mẹrin dípò aguntan kan. Tí kò bá ní ohun tí yóo fi tán ọ̀ràn náà, wọn yóo ta òun fúnra rẹ̀ láti san ohun tí ó jí.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 22

Wo Ẹkisodu 22:1 ni o tọ