Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹrubinrin yìí kò bá wù olówó rẹ̀ láti fi ṣe aya, ó níláti dá a pada fún baba rẹ̀, baba rẹ̀ yóo sì rà á pada. Olówó rẹ̀ kò ní ẹ̀tọ́ láti tà á fún àjèjì nítorí pé òun ló kọ̀ tí kò ṣe ẹ̀tọ́ fún un.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:8 ni o tọ