Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

olówó rẹ̀ yóo mú un wá siwaju Ọlọrun, ní ibi ìlẹ̀kùn àgọ́ tabi òpó ìlẹ̀kùn, olówó rẹ̀ yóo fi òòlù lu ihò sí etí rẹ̀, ẹrú náà yóo sì di tirẹ̀ títí ayé.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:6 ni o tọ