Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹnìkan bá mọ̀ọ́nmọ̀ bá ẹlòmíràn jà, tí ó sì fi ọgbọ́n àrékérekè pa á, bí irú ẹni bẹ́ẹ̀ bá sálọ sí ibi pẹpẹ mi, fífà ni kí ẹ fà á kúrò níbi pẹpẹ náà kí ẹ sì pa á.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:14 ni o tọ