Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 21:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Àwọn òfin tí o gbọdọ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli nìwọ̀nyí:

2. Bí ẹnikẹ́ni bá ra Heberu kan lẹ́rú, ọdún mẹfa ni ẹrú náà óo fi sìn ín, ní ọdún keje, ó níláti dá a sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ láìgba ohunkohun lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21