Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 20:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“O kò gbọdọ̀ pe orúkọ OLUWA Ọlọrun rẹ lásán, nítorí pé, èmi OLUWA yóo dá ẹnikẹ́ni tí ó bá pe orúkọ mi lásán lẹ́bi.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:7 ni o tọ