Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 20:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan náà gbọ́ bí ààrá ti ń sán, tí wọ́n rí i bí mànàmáná ti ń kọ, tí wọ́n gbọ́ dídún ìró fèrè, tí wọ́n rí i tí òkè ń rú èéfín, ẹ̀rù bà wọ́n, wọ́n sì wárìrì. Wọ́n dúró lókèèrè,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:18 ni o tọ