Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ará Ijipti kan ni ó gbà wá kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́-aguntan náà, ó tilẹ̀ tún bá wa pọn omi fún agbo ẹran wa.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:19 ni o tọ