Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọbinrin meje kan wá pọn omi, wọ́n jẹ́ ọmọ Jẹtiro, alufaa ìlú Midiani. Wọ́n pọn omi kún ọpọ́n ìmumi àwọn ẹran, láti fún àwọn agbo ẹran baba wọn ní omi mu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:16 ni o tọ